CinemaO Dobramento do Embrião |
Compre AgoraDe The Biology of Prenatal Development. |
Roteiro: Larin ọsẹ mẹta si mẹrin, awọn eto ẹya ara yio yanju, gẹgẹbi ọpọlọ, ọpa-ẹhin, ati ọkan ọmọ inu oyun naa, eyiti a le fi irọrun damọ lati ẹgbẹ apo ẹyin. Idagbasoke yi ma nmu ki oyun inu ti o ti S̩e pẹrẹsẹ tẹlẹ ri ki o sẹpo. Ilana yi a maa so lara apo ẹyin pọ mọ awọ ti a fi tẹ inu ẹya ara ti ngbe ounjẹ kaakiri ara enia, wọn yio si di aya ati inu ikun ọmọ inu oyun ti ndagba naa. ỌSẸ MẸRIN |
Todas as idades fizeram referência a fecundação, não ao último período menstrual.
|
< Anterior | Veja Instantâneos | Próximo > |