Skip Navigation

Cinema

Camadas Germinativas e Formação de Órgãos


 

14 días

Compre AgoraDe The Biology of Prenatal Development.

Roteiro: Lẹhin ọsẹ meji ati aabọ, ẹpibilasiti yio ti di oriS̩i ẹya ara mẹta, tabi awọ fẹlẹfẹlẹ, ti a npe ni ẹkitodaamu, ẹndodaamu, ati mẹsodaamu.

Ekitodaamu yio di awọn oriS̩iriS̩i ẹya ara bii ọpọlọ, ọpa-ẹhin, iS̩an-ara, awọ-ara, eekanna, ati irun.

Ẹndodaamu yio di awọ ti a fi tẹ inu ẹya ara ti atẹgun ngba lara enia ati ti inu ẹya ara ti ounjẹ ngba, yio si tun di lara oriS̩iriS̩i awọn ẹya ara miran bii ẹdọ ati ẹya ara ti oronro ngbe inu rẹ.

Mẹsodaamu yio di ọkan, kidinrin, egungun, kerekere, iS̩an, ẹjẹ, ati awọn ẹya miran.

Todas as idades fizeram referência a fecundação, não ao último período menstrual.
 <  Anterior       Próximo  > 
Desenvolvimento Humano
Desenvolvimento Humano
Coração e Sistema Circulatório
Coração e Sistema Circulatório
O Dobramento do Embrião
O Dobramento do Embrião
O Dobramento do Embrião
O Dobramento do Embrião
Desenvolvimento do Coração
Desenvolvimento do Coração
O Embrião e o Saco Vitelino
O Embrião e o Saco Vitelino
Previous Set Previous Picture Next Set Next Picture