Skip Navigation

Cinema

DNA


 

Compre AgoraDe The Biology of Prenatal Development.

Roteiro: Awọn eroja mẹrindinlaadọta ti o wa ninu saigọọti duro fun ekini ninu awọn alailẹgbẹ eto igbesi aye ọmọ enia titun. Eto pataki yi wa ninu awọn ohun kan ninu agọ ara ti a npe ni DNA. Ninu wọn ni asẹ fun idagbasoke gbogbo ara enia wa.

Awọn ohun ti a npe ni DNA yi farajọ akaba ti o lọ pọ, ti a npe ni dọbulu hẹlikisi. Lara akasọ ara akaba naa ni awọn ohun kan, ti a npe ni guanini, sitosini, adinini, ati taamini wa.

Guanini yi le darapọ mọ sitosini nikan, adinini si le darapọ mọ taamini.

Todas as idades fizeram referência a fecundação, não ao último período menstrual.
 <  Anterior    Veja Instantâneos    Próximo  > 
DNA
DNA
Da Terra ao Sol Ida e Volta
Da Terra ao Sol Ida e Volta
Fertilização 1
Fertilização 1
Fertilização 2
Fertilização 2
Divisão Celular
Divisão Celular
A Mórula e o Blastocisto
A Mórula e o Blastocisto
Previous Set Previous Picture Next Set Next Picture