CinemaO Coração em Ação |
| Compre AgoraDe The Biology of Prenatal Development. |
|
Roteiro: Ọkan enia ma nmi niwọn igba mẹtalelaadọfa laarin isẹju kan. Sakiyesi bi awọ ara ọkan naa ti nyipada bi ẹjẹ ti nwọ inu awọn iho rẹ, ti o si njade. Ọkan enia maa nmi niwọn igba mẹrinlelaadọta miliọnu ki a to bi ni, ati niwọn igba miliọnu mẹta, o le diẹ ni igbesi aye enia ti o pe ọmọ ọgọrin ọdun. |
|
Todas as idades fizeram referência a fecundação, não ao último período menstrual.
|
| < Anterior | Veja Instantâneos | Próximo > |
|
|




