CinemaO Período Fetal |
| Compre AgoraDe The Biology of Prenatal Development. |
|
Roteiro: Lati igbati ọsẹ mẹjọ ba kọja, titi di opin iloyun, "ọmọ enia ti ndagbasoke ninu yi ni a npe ni fitọọsi,” itumọ eyiti nse "ọmọ ti a ko i tii bi." Ni akoko yi, eyiti a npe ni akoko fitọọsi, gbogbo ẹya-ara ọmọ naa yio dagbasoke sii, wọn yio si maa sisẹ. |
|
Todas as idades fizeram referência a fecundação, não ao último período menstrual.
|
| < Anterior | Veja Instantâneos | Próximo > |
|
|




