CinemaPele Transparente |
| Compre AgoraDe The Biology of Prenatal Development. |
|
Roteiro: Awọ ara ọmọ inu oyun naa ni asiko yi yio mọ gaara nitori pe ko nipọn pupọ. Bi awọ ara naa se nnipọn sii, ni mimọ ti o mọ yio maa dinku, eyiti o tumọ si wipe a le maa wo bi awọn ẹya inu ara ti ndagba, fun osu kan sii. |
|
Todas as idades fizeram referência a fecundação, não ao último período menstrual.
|
| < Anterior | Veja Instantâneos | Próximo > |
|
|




