CinemaCaracterística de Destro e Canhoto |
| Compre AgoraDe The Biology of Prenatal Development. |
|
Roteiro: Ni ọsẹ kẹjọ, iwọn ida marundinlọgọrin ninu ọgọrun ọmọ inu oyun ni maa lo ọwọ ọtun. Awọn yoku ni a le pin si awọn ti yio lo ọwọ osi, ati awọn ti yio lo mejeeji. Eyi ni o kọkọ fi iwa lilo ọwọ ọtun tabi ọwọ osi han. |
|
Todas as idades fizeram referência a fecundação, não ao último período menstrual.
|
| < Anterior | Veja Instantâneos | Próximo > |
|
|




