CinemaMovimento e Sensação |
| Compre AgoraDe The Biology of Prenatal Development. |
|
Roteiro: Ọmọ inu oyun naa le di nkan mu, o le mi ori rẹ siwaju ati sẹhin, o le la ẹnu rẹ, o le gbe ahọn rẹ, o le poS̩e, osi le na. Isan-ara ti o wa ni oju, atẹlẹwọ, ati atẹlẹsẹ ma nmọ ọ lara bi a ba fi ọwọ kan wọn. “Bi a ba rọra fi ọwọ kan gigise,” ọmọ inu oyun yio rọ ibadi rẹ ati orunkun rẹ yio si lẹ ọmọ-ika ẹsẹ rẹ pọ |
|
Todas as idades fizeram referência a fecundação, não ao último período menstrual.
|
| < Anterior | Veja Instantâneos | Próximo > |
|
|




