Skip Navigation

Cinema

A Mórula e o Blastocisto


 

5 días

Compre AgoraDe The Biology of Prenatal Development.

Roteiro: Laarin ọjọ mẹta si mẹrin lẹhin idapọ ẹyin ọkunrin ati obirin, ẹyin naa yio maa pin si ọna pupọ, wọn a ri rogodo, a si npe oyun inu naa nisisiyi ni morula.

Laarin ọjọ mẹrin si marun, iho kan yio waye laarin awọn ẹyin rogodo wọnyi, a si npe oyun inu naa nisisiyi ni bilasitosisiti.

Awọn ẹyin keekeke ti o wa ninu bilasitosisiti yi ni a npe ni akojọpọ ẹyin ti inu, eyiti yio ko ara wọn jọ pọ lati di ori, ara, ati awọn ẹya ara miran ti o S̩e pataki fun idagbasoke ọmọ enia.

Todas as idades fizeram referência a fecundação, não ao último período menstrual.
 <  Anterior    Veja Instantâneos    Próximo  > 
A Mórula e o Blastocisto
A Mórula e o Blastocisto
3 Bilhões de Pares de Bases por Célula
3 Bilhões de Pares de Bases por Célula
Âmnio e Camadas Germinativas
Âmnio e Camadas Germinativas
Desenvolvimento Embrionário Inicial
Desenvolvimento Embrionário Inicial
Desenvolvimento Humano
Desenvolvimento Humano
Coração e Sistema Circulatório
Coração e Sistema Circulatório
Previous Set Previous Picture Next Set Next Picture